Ojo

Lyrics
Ojo to ru si ewuro Lo ro si ireke Se bi saati rahmoni baba ba wa se Asese o la bijun A tun se ni ma le Koriko terin ba te ko ma tun dide Oke agba ni mo gun yi o x4 E ma jen jaabo Oke agba ni mo gun yi o x3 E ma jen jaabo Omo to ba sisi dede O ye ko ni igbadun Adun obe o nbe ninu shasun This one na the part 1 You never see the part 2 We are relevant just like your tattoo Won ni mo saare wa mo saare Mo de tun gbe eni wa, mo gbe eni wa Mo de pe shalewa, pe shalеwa Ko de lo gbe o ti wa, lo gbo ti wa eh Ojo to ru si еwuro Lo ro si ireke Se bi saati rahmoni baba n ba wa se Asese o la bijun A tun se ni ma le Koriko terin ba te ko ma tun dide Oke agba ni mo gun yi o x4 E ma jen jaabo Oke agba ni mo gun yi o x3 E ma jen jaabo Ise leye ile se ko to fin se ise kole Ise looka baba se to fi pooporo sole Ise nla ni mo se kin to pa owo mi wa le Ma je aye ori mi, ma fin amebo mi sole Won ni mo saare wa mo saare Mo de tun gbe eni wa, mo gbe eni wa Mo de pe shalewa, pe shalewa Ko de lo gbe o ti wa, lo gbo ti wa eh Ojo to ru si ewuro Lo ro si ireke Se bi saati rahmoni baba n ba wa se Asese o la bi jun A tun se ni ma le Koriko to terin ba te ko ma tun dide Oke agba ni mo gun yi o x4 E ma jen jaabo Oke agba ni mo gun yi o x3 E ma jen jaabo Oke oke oke E ma jen jaabo Beat, chris, Underscore
Rate this song
0/5.0 - 0 Ratings
Loading comments...
Credits
- Producers
- KrizBeatz