Adedotun

Album cover art for "Adedotun" by Brymo

Brymo - R&B

Adedotun

2 Plays

View Artist

Lyrics

Language:

Verse 1 Awon adan fo loke Wan foka si oju Orun Wan o ma mo ibi won lo Eledua lo n shey ike won Ko keyin si é Oré o O wun o n wa O wa ni waju re Hook Adedotun....... Oyindamola mi....... Ero gbogbo e ba gberin Adedotun o............. Verse 2 Awon adan fo loke Ni igba igba Won ku oju orun Won o ma mo iwun wan n je Eledua lo n sho wan Lo n bo wan Ko pamo si é Oré ooooooo O wa lo sokoto O wa lapo Sokoto Hook Adedotun....... Oyindamola mi....... Ero gbogbo e ba gberin Adedotun o............. (X2) Ko pamo si é Oré o Owun o n wa O wa ni waju re Ore o........

Rate this song

Rate this song

0/5.0 - 0 Ratings

5
0.0% (0)
4
0.0% (0)
3
0.0% (0)
2
0.0% (0)
1
0.0% (0)

Loading comments...

Credits

Writers
  • Brymo