Olorun

Album cover art for "Olorun" by Asake

Asake - Pop, Nigerian Pidgin

Olorun

15.8K Plays

Duration: 2:36

View Artist

Lyrics

Language:

[Intro] Ololade mi Aşakę Emi kọ, Olọrun ma ni Emi kọ, Olọrun ma ni Awa kọ, ọ ọ Emi kọ o Olọrun ma ni [Pre-Chorus] Ta lo gbọn t'Olorun? (Ọmọ ọgbọn) Ko si anybody t'o l'ogbon t'Olorun Ti wọn ba buga ẹ o, ya gba fun Olorun Awọn ti wọn buga mi, wọn ti sa pamọ Wọn ti sa pamọ [Chorus] Emi kọ o, o, Olọrun ma ni o (Ọlọrun ma ni o) Emi kọ o, o, Olọrun ma ni o (Olorun ma ni o) Awa kọ, ọ, Ọlọrun ma ni o (Oh oh oh) Emi kọ o, Olọrun ma ni o [Verse] Ọmọ no be me, şebi na God Carry me from down straight to the top 2020 was real-tough Fall for ground, almost gave up (Gave up) Mo fun won l'Omọ Ope mo dę ję lo o Go naked in my room, I speak to God Baba God, I no sabi all So guide me, as I dey move on on on on [Pre-Chorus] Ta lo gbọn t'Olorun? Ko si anybody t'o l'ogbon t'Olorun Ti wọn ba buga ẹ o, ya gba fun Olorun Awọn ti wọn buga mi, wọn ti sa pamọ Wọn ti sa pamọ [Chorus] Emi kọ o, o, Olọrun ma ni o (Ọlọrun ma ni o) Emi kọ o, o, Olọrun ma ni o (Olorun ma ni o) Awa kọ, ọ, Ọlọrun ma ni o (Oh oh oh) Emi kọ o, Olọrun ma ni o Emi kọ o, o, Olọrun ma ni o (Ọlọrun ma ni o) Emi kọ o, o, Olọrun ma ni o (Olorun ma ni o) Awa kọ, ọ, Ọlọrun ma ni o (Oh oh oh) Emi kọ o, Olọrun ma ni o [Outro] Nkan kan o gbọdọ ş'ọmọ ologo Nkan o gbọdọ mi ọmọ ọlọrun o Alhamdulillah I'm a brand new man Tune in to the King of Sounds and Blues

Rate this song

Rate this song

0/5.0 - 0 Ratings

5
0.0% (0)
4
0.0% (0)
3
0.0% (0)
2
0.0% (0)
1
0.0% (0)

Loading comments...

Credits

Writers
  • Asake