Iya Alariya

Album cover art for "Iya Alariya" by 9ice

9ice - Pop

Iya Alariya

2 Plays

View ArtistView Album

Lyrics

Language:

[Chorus] Emi ni kan kan mowa Moni baba ni igbejo Mo wowo ra Mo gbagbe iyin ola ati egan Iya alariya ken ken, eh-eh Iya alariya ken ken, eh-eh Iya alariya ken ken, ma jo mayo Iya alariya ken ken, eh-eh [Verse 1] Ti moba lo, pelu imo kan Taabi mo re koja lo, pelu inu kan Sa dede ni blessing awa si odo mi tori mo gbagbo Egbegberun subun, lotun losi mi Nkan kan koni se omo olorun Okeere opoju temi Emi ni kankan mowa Moni baba ni igbejo [Chorus] Emi ni kan kan mowa Moni baba ni igbejo Mo wowo ra Mo gbagbe iyin ola ati egan Iya alariya ken ken, eh-eh Iya alariya ken ken, eh-eh Iya alariya ken ken, ma jo mayo Iya alariya kеn ken, eh-eh [Verse 2] Isе owo mi, koni di ibaje Won tie muruwu muruwu mo mi Wan ko fe te Baba ti se ileri, pe ma jaiye mi pe pe pe pe Atele gbe ese n te ono Ajoke aiye, asake orun Koni si mi lono E ye se inu binu si mi ma Mo ni baba ni igbejo [Chorus] Emi ni kan kan mowa Moni baba ni igbejo Mo wowo ra Mo gbagbe iyin ola ati egan Iya alariya ken ken, eh-eh Iya alariya ken ken, eh-eh Iya alariya ken ken, ma jo mayo Iya alariya ken ken, eh-eh

Rate this song

Rate this song

0/5.0 - 0 Ratings

5
0.0% (0)
4
0.0% (0)
3
0.0% (0)
2
0.0% (0)
1
0.0% (0)

Loading comments...

Credits

Writers
  • 9ice
  • King Sunny Adé