Kokanmi

Lyrics
Oni warapa ti rolu magun, khasa Kokanmi, kokanmi Qdot l'oruko mi (kokanmi, kokanmi) Mo mo pe mo mi le shey n f'obo lomi Mio l'ori lo gun pe ibon o le ran mi Bibeli mo ni pelu Qurani Pelu kini baami to dun woro-woro Eni f'oju di ina, ina a jo Iya Ibadan oya gb'agbo le ina Epo ogede ko le yo mi Maape bi Alaafin Oyo ni Werey ni won mo ma le won s'Aro Ma gbe won lo bi dodo Iya Alaro E fun mi ni hammer, kin foh won lori ka Awon werey, awon motherfucker E ro dada k'eto b'eshu lowe E soh fun shigidi, ko ma r'odo lo we Kilonje ko s'ewe ko s'egbo ninu aye? K'Olohun maje a rija aiye ni Shi-o kelebe (kokanmi) Won ni pe Picker die (kokanmi) Pe client o s'oro mo (kokanmi) Pe iyawo yin nshеy olosho (kokanmi) O sun yara Landlord (kokanmi) Won fe mo'di abajo (kokanmi) Tani baba alajo? (Kokanmi) E re ile Babalawo (kokanmi) Ebo yin ma foh m'awo (kokanmi) Woni pе Yahoo ni (kokanmi) Woni pe a sh'ogun owo (kokanmi) Oni warapa rolu magun (kokanmi) Pe Lagbaja bo'ju k'orin (kokanmi) Eni oyinbo o dun lenu mi (kokanmi) But local mi n ja'wo (kokanmi) Oke Kilimanjaro sope Olumo o ga Agbo t'aja, agbo t'eran Ewo ni t'agutan lori aga? Won ni mo local, mo n pa'wo lo Omo Folashade, mo ti gb'ade lo Oyingbo le ma dun lenu mi Eyi tinba soh, Wole Soyinka l'aba yin tu E wa wo eleko to yan odi s'oni moi-moi Oni bugan binu elewa agoyin I don't care if you like or not Eni shishee lo ma pa'wo Kokoro to njo leba ona ni, onilu re nbe ninu igbo Mo ti goke mo ti shee lo k'afara to ja Mo jaapa, k'oyinbo to ja Omode ana ti wa d'agba Qdot, omo imale afeleja E ro dada k'eto b'eshu lowe E soh fun shigidi ko ma r'odo lo we Kilonje ko s'ewe ko s'egbo ninu aye? K'Olohun maje a rija aye ni Shi-o kelebe (kokanmi) Won ni pe Picker die (kokanmi) Pe client o s'oro mo (kokanmi) Pe iyawo yin nshey olosho (kokanmi) O sun yara Landlord (kokanmi) Won fe mo'di abajo (kokanmi) Tani baba alajo? (Kokanmi) E re ile Babalawo (kokanmi) Ebo yin ma foh m'awo (kokanmi) Woni pe Yahoo ni (kokanmi) Woni pe a sh'ogun owo (kokanmi) Oni warapa rolu magun (kokanmi) Pe Lagbaja bo'ju k'orin (kokanmi) Eni oyinbo o dun lenu mi (kokanmi) But local mi n ja'wo (kokanmi) Jirafa jalika ra fali eli malaika mi Orimolade Eni f'oju di ina, ina a jo Iya Ibadan, oya gb'agbo le ina Epo ogede ko le yo mi Maape bi Alaafin Oyo ni K Sir Sosse King of Marley Musa Felix for Garuba Femi Jaguar nilu London Mo mo Baddy Oosha Lanre Typical Milli omo Salawe Mo mo Femi Chill Music Mo mo Billique mo (mo Bili) Mo mo Doctor Brown Mo mo Arowolo Arowolo tin ta motor Mo mo Bottles IBD Dende Alashe Nikas Teni Level Moti mo Water Mo mo Owo Mabo Bunmi simple casher Mo mo Unique Motors Mo mo Climax Mo mo Pasuma Wonder, omo iyawo Anobi l'Omole Xsmile (Yeah, who's here?) Quick as sure boys
Rate this song
0/5.0 - 0 Ratings
Loading comments...
Credits
- Writers
- Qdot Alagbe