Kekere

Album cover art for "Kekere" by Dagrin

Dagrin - Rap

Kekere

0 Plays

Duration: 4:01

View Artist

Lyrics

Language:

[Intro] Won fe sere, won sope mo kere, won ma fe invite mi, ke, won ma sare, ah! Won ni were, oo [Chorus: Dagrin] Won sope mo kere, kekeker Labere kere, awon To jepe won le sere bi mo se nsere Awon tojepe tiwon ba ri Akeke won ma sare, awon toba jepe Tiwon ba l'aroma won ni Were (were 4x) (2x) [Verse 1: Dagrin] Won tun ti de, еmi mofe sanjo, emi mofe sanjo, bi obasanjo, kon sе iro, eni ti o ba ra iro kole ra oto, kati mo ibi to to gba kade mo ona t'oto, mo nsako tori mo l'awon to yii lowo, bi opolo se n sako niwaju elegusi dollar, Gbogbo wa lafe je dollar, patapat ka wa lo se lodo mallam, taba kowo yen de, kawa ma f'owo yen cha-cha, inshort, gbogbo wa la fe, di millionaire [Chorus: Dagrin] Won sope mo kere, kekeker Labere kere, awon To jepe won le sere bi mo se nsere Awon tojepe tiwon ba ri Akeke won ma sare, awon toba jepe Tiwon ba l'aroma won ni Were (were 4x) (2x) [Verse 2: Dagrin] Monday, tuesday and wednesday, thursday, titi di ojo jimoh, olowo laye mo, mo ni mo fe jemo, Oluwa se mi lolowo, eni ba lomo, mi o ti lowo ,won ti nsare gbe rumour, itumo? Abi e dayan mo?/ mo ti de, eti gbere, ok, womi dada, komo bimo se je, duala, biko, ejo talombe?, sukusuku bambam, eni t'oba wu ko be [Chorus: Dagrin] Won sope mo kere, kekeker Labere kere, awon To jepe won le sere bi mo se nsere Awon tojepe tiwon ba ri Akeke won ma sare, awon toba jepe Tiwon ba l'aroma won ni Were (were 4x) (2x) [Verse 3: Dagrin] Emi to je pe, mi o n woju, uche, file!, gbasibe, aunty, bobo oya ki o ko mole, bere mole, mi o ni ki o boso sile, ma wo bose po to, won tobe, ok!, toba jebe, f'oro sile, move your body (body), Shake your body (body), move to the dance floor, sugbon malo fi agbari gbari, ko gba'gidi, ko gba giri-giri/ talon gbemu?, Baba oni waheed, I'm sorry, I'm in a hurry, don't worry, mi o gbori, emi len sori?, A ki n ja kung fu but a je fufu, a nje dundu, a den, mu kunu, Olu! [Chorus: Dagrin] Won sope mo kere, kekeker Labere kere, awon To jepe won le sere bi mo se nsere Awon tojepe tiwon ba ri Akeke won ma sare, awon toba jepe Tiwon ba l'aroma won ni Were (were 4x) (til the song fade)

Rate this song

Rate this song

0/5.0 - 0 Ratings

5
0.0% (0)
4
0.0% (0)
3
0.0% (0)
2
0.0% (0)
1
0.0% (0)

Loading comments...

Credits

Writers
  • Dagrin
  • Heavy L Beatz