Tèmi Nì Tèmi

Lyrics
Ife mi dariji mi Omode n se mi Afarawe O se temi Ka daduro ni mo wari Moti so tele tele ri Igboro O ma rerin ri Ijakadi lo mu nise Karohunwi O bopo sise Bridge Bi nba fa wa n'ole Bi nba tule wan'loro Bi n duro won ma mere Bi nba sa wa ni mo kere Chorus Aba lo aba bo B'ohun won ko para won oh Ohun A ni la n nani Temi Ni Temi Verse 2 Awelewa forijimi Mo lakaka kin to de bi Riro mede O se temi Nibi lile la n b'okunrin Ife re sha lo'n duro timi O dudu, O funfun, O Pupa Ife re sha lo'n munu tumi Ninu erun at'ojo at:ilera Bridge Bi nba fa wa n'ole Bi nba tule wan'loro Bi n duro won ma mere Bi nba sa wa ni mo kere Chorus Aba lo aba bo B'ohun won ko para won oh Ohun A ni la n nani Temi Ni Temi Outro Aba lo aba bo Temi loje lale eni oh Gbogbo igba ti o ba lo Mo mo pe o pada wa
Rate this song
0/5.0 - 0 Ratings
Loading comments...
Credits
- Writers
- Brymo