Ọlanrewaju

Album cover art for "Ọlanrewaju" by Brymo

Brymo - R&B, Alternative

Ọlanrewaju

0 Plays

Duration: 3:26

View Artist

Lyrics

Language:

[Verse 1] Igba o lọ bi orere Bo ba koro oá¹£i maa dun ah Eni to ni suuru kii á¹£eyan kekere Bo ba kan lẹ, oṣi maa goke ah Boo ba ṣe un tọ fe, won maa kẹyin si e (ẹh a ẹh) Bo ba ṣe tirẹ o, o ma jẹ ire fun ẹ [Chorus] Ọlanrewaju ọmọ ọba E ma suure da gba won ni ko o á¹£e were, roora á¹£e Bo ba koro oá¹£i maa dun ah E ma suure da gba oo Olooto ko ni ku si bi ọtẹ ooo Olanrewaju ọmọ mi, e ma suure da gba oo Igba o lọ bi orere Bọmọde oku oo, oṣi maa da gba Ṣọra funja, ṣọ ra fẹgbẹkẹgbẹ Oun tio to o, oṣi maa pọ da nu Gbogbo eni abi lo ma ku Iwa ta a wu lo ma ku Ọlanrewaju ọmọ oba, e ma suure da gba o Won ni ko á¹£e were, roora á¹£e E ma suure da gba oo Olooto ko ni ku sibi ọtẹ oo Ọlanrewaju ọmọ mi, e ma suure da gba o Olooto ko ni ku sipo ika oo Olooto ko ni ku sibi ote oo Ọlanrewaju ọmọ ọba, ee ma suure dagba oo Ọlanrewaju ọmọ mi, ee ma suure da gba oo

Rate this song

Rate this song

0/5.0 - 0 Ratings

5
0.0% (0)
4
0.0% (0)
3
0.0% (0)
2
0.0% (0)
1
0.0% (0)

Loading comments...

Credits

Writers
  • Brymo