Alel�y� M�je

Lyrics
Aleluya meje meje Oselu pejo fun ojo meje Won fe to'lu lojo meje Gbogbo isele korin kese Aleluya meje meje Awon ojelu fere ge Won l'awon omo epa tun tide Won fe darulu mere le Aleluya meje meje Akoni leru won tun ti de Won fe so bose mama gbe Iwo n foku sorun O n sise agbе Gbogbo isele korin kesе Won l'awon omidan lo maye le Won fe jeka won fe roso Oko loma ye okunrin le Bo kowaju si e kota Boba keyin si e kota Boba kuwo nikan se hun o le se Ma gbagbe ibi o ti babo Bo kowaju si e kota Boba keyin si e kota Boba kuwo nikan se hun o le se Ma gbagbe ibi o ti babo Aleluya meje meje (Arere epa epa) Adaleru won tun ti de (Arere epa epa) Ko fe k'omo o mo baba re (Arere epa epa) Ko fe k'oko ko gbo t'aya re (Arere epa epa) Gbogbo isele korin kese (Arere epa epa) Won l'awon omidan lo maye le (Arere epa epa) Won fe jeka won fe roso (Arere epa epa) Oko loma ye okunrin le (Arere epa epa)
Rate this song
0/5.0 - 0 Ratings
Loading comments...
Credits
- Writers
- Brymo