Ominira

Album cover art for "Ominira" by Angélique Kidjo

Angélique Kidjo - Pop

Ominira

0 Plays

Duration: 4:23

View ArtistView Album

Lyrics

Language:

Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a Owa iya iyé é a Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a Owa iya iyé é a Onikaloukou wa n'fè ri ominira Onikaloukou wa n'fè aseyori Onikaloukou wa n'fè ri oyaya Onikaloukou fèlo wa idaji Mmm ewa ka lo Ka lo fè wa tchitchè kori ominira N'tori ominira toro ishè gan Edahoun gbogbo yin foun ominira Aaah ominira, foun min l'owo ka man Lo ominira Aaah ominira, foun min l'owo ka man Lo ominira Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a Owa iya iyé é a Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a Owa iya iyé é a Onikaloukou wa n'fè ri ominira Onikaloukou wa n'fè aséyori Onikaloukou wa n'fè ri oyaya Onikaloukou fèlo wa idaji Ayé wa toro kawa ri ominira Ayé wa fè dada foun gbogbo èniyan Ayé sin wa lodo ominira Mmm ewa ka lo Aaah ominira, foun min l'owo ka man Lo ominira Aaah ominira, foun min l'owo ka man Lo ominira Onikaloukou wa n'fè ri ominira Onikaloukou wa n'fè aséyori Onikaloukou wa n'fè ri oyaya Onikaloukou fèlo wa idaji Ayé wa toro kawa ri ominira Ayé wa fè dada foun gbogbo èniyan Ayé sin wa lodo ominira Mmm ewa ka lo a Aaah ominira, foun min l'owo ka man Lo ominira Aaah ominira, foun min l'owo ka man Lo ominira Aaah ominira Lo, ominira Aaah ominira Lo, ominira Aaah ominira Lo, ominira Aaah ominira Lo, ominira Aaah ominira Lo, ominira Aaah ominira, foun min l'owo ka man Lo ominira Aaah ominira, foun min l'owo ka man Lo ominira

Rate this song

Rate this song

0/5.0 - 0 Ratings

5
0.0% (0)
4
0.0% (0)
3
0.0% (0)
2
0.0% (0)
1
0.0% (0)

Loading comments...

Credits

Credits Not Found