Aisha

Album cover art for "Aisha" by Angélique Kidjo

Angélique Kidjo - Pop, Politics

Aisha

0 Plays

Duration: 2:54

View ArtistView Album

Lyrics

Language:

Aisha, omidan ọla, ma sunkun Aye rẹ, o wa niwaju ẹ Onikaluku wa, gbogbo wa ni ododo Aisha, wahala ni aye Gbadun ni aye, ọjọjumọ ni o Oju ọjọ k'a maa dupẹ o Ọmọde maa sunkun, aye yii o daa Fi ogun silẹ, ma lọ Aisha, omidan ọla, ma sunkun Aye rẹ, o wa niwaju ẹ, ọmọde Onikaluku wa ma jẹ ẹjọ ninu aye Onikaluku yoo duro fun ẹsan ọmọ Aisha, ma lọ Aisha, omidan ọla Ọmọde, wa k'a lọ Omọde, onikaluku wa l'ahun wa ododo [?] Aisha Aisha

Rate this song

Rate this song

0/5.0 - 0 Ratings

5
0.0% (0)
4
0.0% (0)
3
0.0% (0)
2
0.0% (0)
1
0.0% (0)

Loading comments...

Credits

Producers
  • Angélique Kidjo
  • Jean Hébrail